MORE VIDEOS
Explore more
Shorts Create


Mo dupe lowo Olodumare to Ṣọ mi di igbayi pelu Ilosiwaju ati Alafia . Modupe Afikun, modupe Ayokuro . Modupe fun aya mi DamiLola Bisuga Soyoye modupe fun iya mi Olaitan Soyoye . Mo tun dupe fun Awon omo mi . Ati Ojulumo pelu awon ore to nife mi denu. Ki Olodumare gba gbogbo Ogo . Aṣé . Mo ku Ojo Ibi (Happy birthday to me) .mo ti di omo odun mẹ́tàlélọ́gbọ̀n 😃.
Comments
Show more